Ìfihàn 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn èyí mo tún rí angẹli tí ó ń ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ bọ̀. Ó ní àṣẹ ńlá. Gbogbo ayé mọ́lẹ̀ nítorí ẹwà ògo rẹ̀.

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:1-3