Ìfihàn 17:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ àṣírí kan wà níwájú rẹ̀, ìtumọ̀ rẹ̀ ni: “Babiloni ìlú ńlá, ìyá àwọn àgbèrè ati oríṣìíríṣìí ohun ẹ̀gbin ayé.”

Ìfihàn 17

Ìfihàn 17:1-10