Ìfihàn 16:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá gbọ́ tí pẹpẹ ìrúbọ wí pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, Oluwa, Ọlọrun, Olodumare, òtítọ́ ati òdodo ni ìdájọ́ rẹ.”

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:1-9