Ìfihàn 16:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli kẹta da ohun tí ó wà ninu àwo rẹ̀ sinu odò ati sinu ìsun omi, ó bá di ẹ̀jẹ̀.

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:1-8