Ìfihàn 16:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí olè ni mò ń bọ̀. Ẹni tí ó bá ń ṣọ́nà ṣe oríire, tí olúwarẹ̀ wọ aṣọ rẹ̀, kí ó má baà sí ní ìhòòhò, kí ojú má baà tì í níwájú àwọn eniyan.”

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:5-21