Ìfihàn 16:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá rí àwọn ẹ̀mí burúkú mẹta kan, wọ́n dàbí ọ̀pọ̀lọ́ ní ẹnu Ẹranko Ewèlè náà, ati ní ẹnu wolii èké náà.

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:4-21