Ìfihàn 16:11 BIBELI MIMỌ (BM)

wọn bá bẹ̀rẹ̀ sí sọ ọ̀rọ̀ àfojúdi sí Ọlọrun ọ̀run nítorí ìrora wọn ati nítorí egbò ara wọn, dípò kí wọ́n ronupiwada fún ohun tí wọ́n ti ṣe.

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:7-14