Ìfihàn 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli kẹta wá tẹ̀lé wọn. Ó kígbe pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá júbà ẹranko náà ati ère rẹ̀, tí ó gba àmì rẹ̀ siwaju rẹ̀ tabi sí ọwọ́ rẹ̀,

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:1-14