Ìfihàn 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá kígbe pé, “Ẹ bẹ̀rù Ọlọrun kí ẹ sì fi ògo fún un, nítorí àkókò ìdájọ́ rẹ̀ dé! Ẹ júbà ẹni tí ó dá ọ̀run ati ayé, òkun ati gbogbo orísun omi.”

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:1-13