Ìfihàn 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sì gbọ́ ohùn kan láti ọ̀run bí ìró ọpọlọpọ omi ati bí ìgbà tí ààrá líle bá ń sán. Ohùn tí mo gbọ́ ni ti àwọn oníhapu tí wọn ń lu hapu wọn.

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:1-8