Ìfihàn 14:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni angẹli tí ó ní dòjé náà bá ti dòjé rẹ̀ bọ inú ilé ayé, ó bá kó èso àjàrà ayé jọ, ó dà wọ́n sí ibi ìfúntí ibinu ńlá Ọlọrun.

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:10-20