Ìfihàn 14:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá rí ìkùukùu funfun. Ẹnìkan tí ó dàbí ọmọ eniyan jókòó lórí ìkùukùu náà. Ó dé adé wúrà. Ó mú dòjé tí ó mú lọ́wọ́.

Ìfihàn 14

Ìfihàn 14:7-18