Ìfihàn 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

A fún un ní agbára láti gbógun ti àwọn eniyan Ọlọrun ati láti ṣẹgun wọn. A tún fún un ní àṣẹ lórí gbogbo ẹ̀yà ati orílẹ̀-èdè ati oríṣìíríṣìí èdè ati gbogbo eniyan.

Ìfihàn 13

Ìfihàn 13:6-9