Ìfihàn 12:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú wá bí Ẹranko Ewèlè yìí sí obinrin náà. Ó wá lọ gbógun ti àwọn ọmọ rẹ̀ yòókù, tí wọn ń pa àṣẹ Ọlọrun mọ́, tí wọn ń jẹ́rìí igbagbọ ninu Jesu.

Ìfihàn 12

Ìfihàn 12:13-18