Ìfihàn 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wá rí àmì ńlá kan ní ọ̀run. Obinrin kan tí ó fi oòrùn ṣe aṣọ, tí òṣùpá wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀. Ó dé adé tí ó ní ìràwọ̀ mejila.

Ìfihàn 12

Ìfihàn 12:1-5