Ìfihàn 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan láti inú gbogbo ẹ̀yà, ati gbogbo orílẹ̀-èdè yóo máa wo òkú wọn fún ọjọ́ mẹta ati ààbọ̀. Wọn kò ní jẹ́ kí wọ́n sin wọ́n.

Ìfihàn 11

Ìfihàn 11:3-18