Ìfihàn 11:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wá gbọ́ ohùn líle láti ọ̀run wá tí ó sọ fún wọn pé, “Ẹ gòkè wá síhìn-ín.” Ni wọ́n bá gòkè lọ sọ́run ninu ìkùukùu, lójú àwọn ọ̀tá wọn.

Ìfihàn 11

Ìfihàn 11:3-19