Ìfihàn 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo tún gbọ́ ohùn kan láti ọ̀run tí ó sọ fún mi pé, “Lọ gba ìwé tí ó wà ni ṣíṣí tí ó wà lọ́wọ́ angẹli tí ó dúró lórí òkun ati lórí ilẹ̀.”

Ìfihàn 10

Ìfihàn 10:2-11