Ìfihàn 10:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú ìwé kékeré kan lọ́wọ́ tí ó wà ní ṣíṣí. Ó gbé ẹsẹ̀ ọ̀tún rẹ̀ lé orí òkun, ó sì gbé ti òsì lé orí ilẹ̀ ayé.

Ìfihàn 10

Ìfihàn 10:1-5