Ìfihàn 10:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá sọ fún mi pé, “O níláti tún kéde fún ọ̀pọ̀ àwọn eniyan ati oríṣìíríṣìí ẹ̀yà ati àwọn orílẹ̀-èdè, ati ọpọlọpọ ìjọba.”

Ìfihàn 10

Ìfihàn 10:9-11