Ìfihàn 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Èmi ni Alfa ati Omega, ìbẹ̀rẹ̀ ati òpin.” Oluwa Ọlọrun ló sọ bẹ́ẹ̀, ẹni tí ó ti wà, tí ń bẹ, tí ó sì tún ń bọ̀ wá, Olodumare.

Ìfihàn 1

Ìfihàn 1:5-11