Ìfihàn 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú ìràwọ̀ meje lọ́wọ́ ọ̀tún rẹ̀. Idà olójú meji tí ó mú yọ jáde lẹ́nu rẹ̀. Ojú rẹ̀ mọ́lẹ̀ bí oòrùn ọ̀sán gangan.

Ìfihàn 1

Ìfihàn 1:11-17