Ìfihàn 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ààrin àwọn ọ̀pá fìtílà yìí ni ẹnìkan wà tí ó dàbí eniyan. Ó wọ ẹ̀wù tí ó balẹ̀ dé ilẹ̀. Ó fi ọ̀já wúrà gba àyà.

Ìfihàn 1

Ìfihàn 1:4-19