Ìṣe Àwọn Aposteli 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin tí ó ń bá a rìn dúró. Wọn kò sọ ohunkohun. Wọ́n ń gbọ́ ohùn eniyan, ṣugbọn wọn kò rí ẹnìkankan.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:3-12