Ìṣe Àwọn Aposteli 9:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò yìí ó wá ṣàìsàn, ó sì kú. Wọ́n bá wẹ̀ ẹ́, wọ́n tẹ́ ẹ sí yàrá lókè ní ilé pẹ̀tẹ́ẹ̀sì kan.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:35-43