Ìṣe Àwọn Aposteli 9:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Peteru tí ń lọ káàkiri láti ibìkan dé ibi keji, ó dé ọ̀dọ̀ àwọn eniyan Ọlọrun tí wọn ń gbé ìlú Lida.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:22-38