Ìṣe Àwọn Aposteli 9:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá jẹun, ara rẹ̀ bá tún mókun. Ó wà pẹlu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu tí ó wà ní Damasku fún ọjọ́ díẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:9-27