Ìṣe Àwọn Aposteli 9:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Oluwa sọ fún un pé, “Lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, nítorí mo ti yàn án láti mú orúkọ mi lọ siwaju àwọn orílẹ̀-èdè yòókù ati àwọn ọba wọn ati àwọn ọmọ Israẹli.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:13-17