Ìṣe Àwọn Aposteli 9:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Anania dáhùn pé, “Oluwa, mo ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ọkunrin yìí lẹ́nu ọpọlọpọ eniyan: oríṣìíríṣìí ibi ni ó ti ṣe sí àwọn eniyan mímọ́ rẹ ní Jerusalẹmu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Ìṣe Àwọn Aposteli 9:3-21