Ìṣe Àwọn Aposteli 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan ṣù bo Filipi kí wọ́n lè gbọ́ ọ̀rọ̀ tí ó ń sọ, wọ́n sì ń rí iṣẹ́ abàmì tí ó ń ṣe.

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:1-15