Ìṣe Àwọn Aposteli 8:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwẹ̀fà náà bá pàṣẹ pé kí ọkọ̀ dúró. Òun ati Filipi bá sọ̀kalẹ̀, wọ́n lọ sinu odò, Filipi bá rì í bọmi.

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:34-40