Ìṣe Àwọn Aposteli 8:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli Oluwa sọ fún Filipi pé, “Dìde kí o lọ sí apá gúsù, ní ọ̀nà tí ó lọ láti Jerusalẹmu sí Gasa.” (Aṣálẹ̀ ni ọ̀nà yìí gbà lọ.)

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:21-29