Ìṣe Àwọn Aposteli 8:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Simoni dá Peteru lóhùn pé, “Ẹ gbadura sí Oluwa fún mi kí ohunkohun tí ẹ wí má ṣẹlẹ̀ sí mi.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:22-30