Ìṣe Àwọn Aposteli 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Simoni rí i pé ọwọ́ tí àwọn aposteli gbé lé wọn ni ó mú kí wọ́n rí Ẹ̀mí gbà, ó fi owó lọ̀ wọ́n.

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:13-27