Ìṣe Àwọn Aposteli 8:16 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí Ẹ̀mí Mímọ́ kò ì tíì bà lé ẹnikẹ́ni ninu wọn. Ìrìbọmi ní orúkọ Oluwa Jesu nìkan ni wọ́n ṣe.

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:15-25