Ìṣe Àwọn Aposteli 8:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Simoni náà gbàgbọ́, ó ṣe ìrìbọmi, ni ó bá fara mọ́ Filipi. Nígbà tí ó rí iṣẹ́ abàmì ati iṣẹ́ ìyanu ńlá tí ó ń ṣe, ẹnu yà á.

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:5-17