Ìṣe Àwọn Aposteli 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo eniyan ló kà á kún; ati àwọn eniyan yẹpẹrẹ ati àwọn eniyan pataki wọn. Wọ́n ní, “Eléyìí ní agbára Ọlọrun tí à ń pè ní ‘Agbára ńlá.’ ”

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:1-16