Ìṣe Àwọn Aposteli 7:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun wá bá a dá majẹmu, ó fi ilà kíkọ ṣe àmì majẹmu náà. Nígbà tí ó bí Isaaki, ó kọ ọ́ nílà ní ọjọ́ kẹjọ. Isaaki bí Jakọbu. Jakọbu bí àwọn baba-ńlá wa mejila.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:7-9