Ìṣe Àwọn Aposteli 7:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin yìí ni ẹ gba òfin Ọlọrun láti ọwọ́ àwọn angẹli, ṣugbọn ẹ kò pa òfin náà mọ́.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:45-60