Ìṣe Àwọn Aposteli 7:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí àtíbàbà Moleki ni ẹ gbé rù,ati ìràwọ̀ Refani oriṣa yín,àwọn ère tí ẹ ṣe láti máa foríbalẹ̀ fún?N óo le yín lọ sí ìgbèkùn, ẹ óo kọjá Babiloni.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:36-46