Ìṣe Àwọn Aposteli 7:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá ṣe ère ọmọ mààlúù kan ní àkókò náà, wọ́n rúbọ sí i. Wọ́n bá ń ṣe àríyá lórí ohun tí wọ́n fi ọwọ́ wọn ṣe.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:39-48