Ìṣe Àwọn Aposteli 7:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose yìí ni aṣaaju wọn, tí ó ṣe iṣẹ́ ìyanu ati iṣẹ́ abàmì ní ilẹ̀ Ijipti ní Òkun Pupa ati ní ilẹ̀ aṣálẹ̀ fún ogoji ọdún.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:29-39