Ìṣe Àwọn Aposteli 7:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Oluwa tún sọ fún un pé, ‘Bọ́ sálúbàtà tí ó wà lẹ́sẹ̀ rẹ, nítorí ilẹ̀ mímọ́ ni ibi tí o dúró sí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:26-37