Ìṣe Àwọn Aposteli 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún un pé, ‘Jáde kúrò ní ilẹ̀ rẹ, láàrin àwọn ẹbí rẹ, kí o lọ sí ilẹ̀ tí èmi yóo fihàn ọ́.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:1-5