Ìṣe Àwọn Aposteli 7:23 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí Mose di ẹni ogoji ọdún, ó pinnu pé òun yóo lọ bẹ àwọn ará òun, àwọn ọmọ Israẹli, wò.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:22-27