Ìṣe Àwọn Aposteli 7:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu bá ranṣẹ láti pe Jakọbu baba rẹ̀ wá ati gbogbo àwọn ẹbí rẹ̀. Wọ́n jẹ́ eniyan marunlelaadọrin (75).

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:5-21