Ìṣe Àwọn Aposteli 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, ìyàn mú ní gbogbo ilẹ̀ Ijipti ati ní ilẹ̀ Kenaani. Eléyìí mú ìṣòro pupọ wá. Àwọn eniyan wa kò bá rí oúnjẹ jẹ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:2-13