Ìṣe Àwọn Aposteli 6:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Stefanu ń ṣe iṣẹ́ ìyanu ati iṣẹ́ abàmì ńlá láàrin àwọn eniyan nítorí pé ẹ̀bùn ati agbára Ọlọrun pọ̀ lọ́wọ́ rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Ìṣe Àwọn Aposteli 6:4-15