Ìṣe Àwọn Aposteli 5:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru bi í pé, “Sọ fún mi, ṣé iye tí ẹ ta ilẹ̀ náà nìyí?”Ó dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, iye tí a tà á ni.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:6-10