Ìṣe Àwọn Aposteli 5:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Farisi kan ninu àwọn ìgbìmọ̀ dìde. Orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Gamalieli, olùkọ́ nípa ti òfin ni, ó lókìkí láàrin gbogbo àwọn eniyan. Ó ní kí àwọn ọkunrin náà jáde fún ìgbà díẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Ìṣe Àwọn Aposteli 5:26-35